Matthew 8:13
13
Nítorí náà Jesu sì wí fún balógun ọ̀run náà pé,
“Máa lọ ilé, ohun tí ìwọ gbàgbọ́ ti rí bẹ́ẹ̀.”
A sì mú ọmọ ọ̀dọ̀ náà láradá ní wákàtí kan náà.
Copyright information for
YorBMYO